Proverb
Àgbájọ ọwọ́ la fi ń’sọ àyà.
Translation
[With] All hands together we beat the chest in solidarity.
Postproverbials
-
Postproverbial: Àgbájọ ọwọ́ la fi ń’sọ àyà; l’áyée kòró kọ̀ọ́.
Translation: [With] All hands together we beat the chest in solidarity; not in the age of coronavirus.
-
Postproverbial: Àgbájọ ọwọ́ la fi ń’wẹ ọwọ́.
Translation: [With] All hands together we wash (the hands) to cleanliness.
Language
Africa (COVID-19)
Tags
beat
hand
together
chest