Proverb
Ìsúnmọ́ni, là á mọ̀ ṣe ẹni.
Translation
Close association brings understanding.
Comment
Language - Yoruba
Postproverbials
-
Postproverbial: Ìsúnmọ́ni, àrùn níí dá sára.
Translation: Close association breeds illness.
Language
Africa (COVID-19)
Tags
solidarity
unity
association
understanding