Proverb
Tí ará ilé ẹni bá ń’jẹ kòkòrò burúkú, tí kò bá r’ẹ́ni sọ fun un, hùrùhẹrẹ rẹ̀ kò ní jẹ́ kí ará ilé gbádùn.
Translation
When one’s relation feeds on a forbidden insect without being warned, his restive reaction will not allow the neighbours to rest.
Postproverbials
-
Postproverbial: Tí ará China bá ń’jẹ kòkòrò burúkú, tí kò bá r’ẹ́ni sọ fún un, kòró kò ní jẹ́ kí gbogbo àgbáyé gbádùn.
Translation: When the Chinese feeds on forbidden animals without being warned, the coronavirus will not allow the whole world to rest.
Language
Africa (COVID-19)
Tags
eat
person
rest
insect
neighbour
neighbor