Skip to main content
Toggle navigation
Home
About us
About
Lists
Privacy Policy
Collaborators
What is Postproverbial?
Postproverbials
Proverbs
News/Events
Contact
Search
Home
»
Lists
»
List of Proverbs
List of Proverbs
Igi gogoro má gún mi lójú, àtòkèrè latí n wòó.
Ibi pẹlẹbẹ ni a ti ń mú ọ̀ọ̀lẹ̀ jẹ.
Ìbàjẹ́ ọjọ́ kan, kì í tán l’ógún ọdún.
Gàǹbàrí pa Fúlàní, kò lẹ́jọ́ nínú.
Ẹyin ni ń di àkùkọ.
Èṣúrú ṣ’àṣejù, ó tẹ́ l’ọ́wọ́ oníyán.
Ẹṣin iwájú, ni t’ẹ̀yìn ń wò sáré.
Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.
Ẹni tó gbódó mì, ìdúró kò sí, ìbere kò sí.
Ẹni tó gbépo lájà kò jalè bí eni tí ó gbà á síle.
« first
‹ previous
…
3
4
5
6
7
8
9
10
11
…
next ›
last »