Skip to main content
Toggle navigation
Home
About us
About
Lists
Privacy Policy
Collaborators
What is Postproverbial?
Postproverbials
Proverbs
News/Events
Contact
Search
Home
»
Lists
»
List of Proverbs
List of Proverbs
Ẹni tó bá forí tì í títí dé òpin, ni à ó gbàlà.
Ẹni tó fò sókè, ó bẹ́ ijó lórí.
Ẹni tí yóò j'oyin inú àpáta, kìí w’enu àáké.
Ẹni tí kò mọ ibi t’ẹ́gbẹ́ ẹ̀ ti là, yóò wulẹ̀ sáré kú.
Ẹni tí ẹ̀gún bá gún l’ẹ́sẹ̀, níí ṣe lákáńlàká tọ alábẹ.
Ẹni tí a bá torí ẹ̀ pa Adìyẹ , iwe ni ó ń’jẹ.
Ẹnìkan kì í jẹ́ kí ilẹ̀ ó fẹ̀.
Ẹnìkan kì í jẹ́ “Àwa dé”.
Ẹni bá t’ajà èèpẹ̀, yí ò gbowó òkúta.
Ẹlẹ́nu rírùn ló ni àmù ìyá a rẹ̀.
« first
‹ previous
…
4
5
6
7
8
9
10
11
12
…
next ›
last »