Postproverbials

Postproverbial: Ojú ló mọ ohun tó l’óyún.
Translation: The eye-gauge will tell which person or thing is pregnant.
Proverb: Ojú ló mọ ohun tó yó’nú.
Translation: The eye-gauge will tell which meal will be satisfying.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú kò yá bù sán, pupa ló se é dín dòdò.
Translation: (As) the unripe plantain is not fit for consumption, only the ripe one is good for frying.
Proverb: Ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú kò yá bù sán, Ọmọ burúkú kò yá lù pa.
Translation: (As) the unripe plantain is not fit for consumption, (so) it is not easy to beat the irresponsible child to death.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ọbẹ̀ tó dùn, owó Ọlọ́pàá!
Translation: The delicious stew, the policeman’s wealth!
Proverb: Ọbẹ̀ tó dùn, owó ló pa á.
Translation: The delicious stew, is made possible by cash.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ọbẹ̀ tó dùn, mummy ló sè é
Translation: The delicious stew, is prepared by mother.
Proverb: Ọbẹ̀ tó dùn, owó ló pa á.
Translation: The delicious stew, is made possible by cash.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ọbẹ̀ tí baálé ilé kìí jẹ, ẹran inú rẹ̀ ni kò pọ̀.
Translation: The stew that is forbidden to the husband, is only lacking in sauce and assorted meat.
Proverb: Ọbẹ̀ tí baálé ilé kìí jẹ, ìyálé ilé kìí sè é.
Translation: The stew that is forbidden to the husband, the senior wife does not cook it.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ọbẹ̀ kìí mì ní ikùn àgbà, àmọ́, ó ń mì tí àgbà bá sáré.
Translation: The soup does not shake in the belly of the elder; it does shake when the elder runs.
Proverb: Ọbẹ̀ kìí mì ní ikùn àgbà.
Translation: The soup does not shake in the belly of the elder.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ológun tó bá mọ̀’jà mọ̀’sá níí t’ọ́jọ́.
Translation: The warrior who knows when to retreat and when to fight will live longer.
Proverb: Mọ̀‘jà mọ̀’sá là á mọ akínkanjú; akínkanjú tó mọ̀’jà tí ò mọ̀’sá, irú wọn níí b’ógun lọ.
Translation: Attack and retreat is the stuff of a great warrior; the warrior who knows how to fight but doesn’t know when to retreat will die with the war.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Màlúù tí kò ní’rù, ó wà ní Sábó.
Translation: The cow that has no tail is available at Sabo.
Proverb: Màlúù tí kò ní’rù, Olúwa níí bá a léṣinṣin.
Translation: As for the cow that has no tail, God is its repellant against flies.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Màlúù tí kò ní’rù, ó wà ní Kárà.
Translation: The cow that has no tail is available in Kara.
Proverb: Màlúù tí kò ní’rù, Olúwa níí bá a léṣinṣin.
Translation: As for the cow that has no tail, God is its repellant against flies.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Màlúù tí kò ní’rù, ó wà ní Sángo.
Translation: The cow that has no tail is available in Sanngo.
Proverb: Màlúù tí kò ní’rù, Olúwa níí bá a léṣinṣin.
Translation: As for the cow that has no tail, God is its repellant against flies.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more